- 
	                        
            
            Àìsáyà 44:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 Ẹni tó ń sọ fún ibú omi pé, ‘Gbẹ, Màá sì mú kí gbogbo odò rẹ gbẹ táútáú’;+ - 
	                        
            
            Jeremáyà 51:36, 37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        36 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: Màá mú kí omi òkun rẹ̀ gbẹ, màá sì mú kí àwọn kànga rẹ̀ gbẹ.+ 
 
- 
                                        
 
- 
	                        
            
            
 
-