Àìsáyà 13:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+ Àìsáyà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àwọn ẹranko tó ń hu á máa ké nínú àwọn ilé gogoro rẹ̀Àti àwọn ajáko* nínú àwọn ààfin rẹ̀ tó lọ́lá. Àkókò rẹ̀ ti sún mọ́lé, a ò sì ní fi kún àwọn ọjọ́ rẹ̀.”+
19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+
22 Àwọn ẹranko tó ń hu á máa ké nínú àwọn ilé gogoro rẹ̀Àti àwọn ajáko* nínú àwọn ààfin rẹ̀ tó lọ́lá. Àkókò rẹ̀ ti sún mọ́lé, a ò sì ní fi kún àwọn ọjọ́ rẹ̀.”+