Ìsíkíẹ́lì 23:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Torí náà, ìwọ Òhólíbà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èmi yóò ru àwọn olólùfẹ́ rẹ sókè,+ àwọn tí o* kórìíra tí o sì fi sílẹ̀, èmi yóò sì mú kí wọ́n kọjú ìjà sí ọ láti ibi gbogbo,+ Ìsíkíẹ́lì 23:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Wọ́n á bọ́ aṣọ lára rẹ,+ wọ́n á sì gba ohun ọ̀ṣọ́ rẹ.+
22 “Torí náà, ìwọ Òhólíbà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èmi yóò ru àwọn olólùfẹ́ rẹ sókè,+ àwọn tí o* kórìíra tí o sì fi sílẹ̀, èmi yóò sì mú kí wọ́n kọjú ìjà sí ọ láti ibi gbogbo,+