Jeremáyà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà tí o bá sì sọ ní ọkàn rẹ pé, ‘Kí ló dé tí àwọn nǹkan yìí fi ṣẹlẹ̀ sí mi?’+ Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ tó pọ̀ ni wọ́n ṣe ká aṣọ rẹ sókè +Tí wọ́n sì fìyà jẹ gìgísẹ̀ rẹ. Ìfihàn 17:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ìwo mẹ́wàá+ tí o rí àti ẹranko náà,+ máa kórìíra aṣẹ́wó náà,+ wọ́n máa sọ ọ́ di ahoro, wọ́n á tú u sí ìhòòhò, wọ́n máa jẹ ẹran ara rẹ̀, wọ́n sì máa fi iná sun ún pátápátá.+
22 Nígbà tí o bá sì sọ ní ọkàn rẹ pé, ‘Kí ló dé tí àwọn nǹkan yìí fi ṣẹlẹ̀ sí mi?’+ Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ tó pọ̀ ni wọ́n ṣe ká aṣọ rẹ sókè +Tí wọ́n sì fìyà jẹ gìgísẹ̀ rẹ.
16 Ìwo mẹ́wàá+ tí o rí àti ẹranko náà,+ máa kórìíra aṣẹ́wó náà,+ wọ́n máa sọ ọ́ di ahoro, wọ́n á tú u sí ìhòòhò, wọ́n máa jẹ ẹran ara rẹ̀, wọ́n sì máa fi iná sun ún pátápátá.+