Jeremáyà 50:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ìró ogun wà ní ilẹ̀ náà,Àjálù ńlá. 23 Ẹ wo bí wọ́n ṣe ṣẹ́ òòlù irin* gbogbo ayé, tí wọ́n sì fọ́ ọ!+ Ẹ wo bí Bábílónì ṣe di ohun àríbẹ̀rù láàárín àwọn orílẹ̀-èdè!+
22 Ìró ogun wà ní ilẹ̀ náà,Àjálù ńlá. 23 Ẹ wo bí wọ́n ṣe ṣẹ́ òòlù irin* gbogbo ayé, tí wọ́n sì fọ́ ọ!+ Ẹ wo bí Bábílónì ṣe di ohun àríbẹ̀rù láàárín àwọn orílẹ̀-èdè!+