Àìsáyà 21:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi: Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,Apanirun sì ń pani run. Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+ Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+
2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi: Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,Apanirun sì ń pani run. Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+ Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+