ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 137:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 137 Létí àwọn odò Bábílónì,+ ibẹ̀ la jókòó sí.

      A sunkún nígbà tí a rántí Síónì.+

  • Àìsáyà 14:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé:

      “Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́!

      Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+

  • Àìsáyà 14:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Gbogbo ayé ti wá sinmi, ó bọ́ lọ́wọ́ ìyọlẹ́nu.

      Àwọn èèyàn ń kígbe ayọ̀.+

  • Àìsáyà 35:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+

      Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+

      Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,

      Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́