2 Kíróníkà 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn náà, ó ṣe òpó méjì+ síwájú ilé náà, gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùndínlógójì (35), ọpọ́n tó wà lórí òpó kọ̀ọ̀kan sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún.+
15 Lẹ́yìn náà, ó ṣe òpó méjì+ síwájú ilé náà, gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùndínlógójì (35), ọpọ́n tó wà lórí òpó kọ̀ọ̀kan sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún.+