ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 18:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Torí náà, ilẹ̀ náà jẹ́ aláìmọ́, màá fìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ jẹ ẹ́, ilẹ̀ náà yóò sì pọ àwọn tó ń gbé ibẹ̀ jáde.+

  • Léfítíkù 26:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run.

  • Diutarónómì 28:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Jèhófà máa lé ìwọ àti ọba tí o bá fi jẹ lórí ara rẹ lọ sí orílẹ̀-èdè tí ìwọ àtàwọn baba ńlá rẹ kò mọ̀,+ o sì máa sin àwọn ọlọ́run míì níbẹ̀, àwọn ọlọ́run tí wọ́n fi igi àti òkúta+ ṣe.

  • Àìsáyà 24:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Wọ́n máa mú kí ilẹ̀ náà ṣófo pátápátá;

      Wọ́n máa kó gbogbo ẹrù rẹ̀,+

      Torí Jèhófà ti sọ ọ̀rọ̀ yìí.

  • Jeremáyà 25:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Màá ránṣẹ́ pe gbogbo ìdílé tó wà ní àríwá,”+ ni Jèhófà wí, “màá ránṣẹ́ sí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì, ìránṣẹ́ mi,+ màá mú wọn wá láti gbéjà ko ilẹ̀ yìí+ àti àwọn tó ń gbé lórí rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo orílẹ̀-èdè tó yí i ká.+ Màá pa wọ́n run pátápátá, màá sì sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù àti ohun àrísúfèé àti ibi àwókù títí láé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́