ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 26:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Èmi yóò mú idà ẹ̀san wá sórí yín torí ẹ da májẹ̀mú+ náà. Tí ẹ bá kóra jọ sínú àwọn ìlú yín, èmi yóò rán àrùn sí àárín yín,+ màá sì mú kí ọwọ́ àwọn ọ̀tá yín tẹ̀ yín.+

  • Jeremáyà 9:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 “Ǹjẹ́ kò yẹ kí n pè wọ́n wá jíhìn nítorí nǹkan wọ̀nyí?” ni Jèhófà wí.

      “Ǹjẹ́ kò yẹ kí n* gbẹ̀san lára orílẹ̀-èdè tó ṣe irú èyí?+

  • Jeremáyà 44:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Níkẹyìn, Jèhófà kò lè fara da ìwà ibi yín mọ́ àti àwọn ohun ìríra tí ẹ ti ṣe, torí náà ilẹ̀ yín pa run, ó di ohun àríbẹ̀rù àti ègún, kò sì sí ẹnikẹ́ni tó ń gbé ibẹ̀, bó ṣe rí lónìí yìí.+

  • Náhúmù 1:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo,+ ó sì ń gbẹ̀san;

      Jèhófà ń gbẹ̀san, ó sì ṣe tán láti bínú.+

      Jèhófà ń gbẹ̀san lára àwọn elénìní rẹ̀,

      Ó sì ń to ìbínú rẹ̀ jọ de àwọn ọ̀tá rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́