Jeremáyà 39:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Gbogbo ìjòyè ọba Bábílónì wọlé, wọ́n sì jókòó ní Ẹnubodè Àárín,+ àwọn ni, Nẹgali-ṣárésà tó jẹ́ Samugari, Nebo-sásékímù tó jẹ́ Rábúsárísì,* Nẹgali-ṣárésà tó jẹ́ Rábúmágì* àti gbogbo àwọn tó kù lára àwọn ìjòyè ọba Bábílónì.
3 Gbogbo ìjòyè ọba Bábílónì wọlé, wọ́n sì jókòó ní Ẹnubodè Àárín,+ àwọn ni, Nẹgali-ṣárésà tó jẹ́ Samugari, Nebo-sásékímù tó jẹ́ Rábúsárísì,* Nẹgali-ṣárésà tó jẹ́ Rábúmágì* àti gbogbo àwọn tó kù lára àwọn ìjòyè ọba Bábílónì.