Jeremáyà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí ‘mò ń pe gbogbo ìdílé àwọn ìjọba àríwá,’ ni Jèhófà wí,+‘Wọ́n á wá, kálukú wọn á sì ṣe ìtẹ́ rẹ̀Sí àwọn ẹnubodè Jerúsálẹ́mù,+Wọ́n á gbé e ti gbogbo ògiri tó yí i káWọ́n á sì gbé e ti gbogbo ìlú tó wà ní Júdà.+
15 Nítorí ‘mò ń pe gbogbo ìdílé àwọn ìjọba àríwá,’ ni Jèhófà wí,+‘Wọ́n á wá, kálukú wọn á sì ṣe ìtẹ́ rẹ̀Sí àwọn ẹnubodè Jerúsálẹ́mù,+Wọ́n á gbé e ti gbogbo ògiri tó yí i káWọ́n á sì gbé e ti gbogbo ìlú tó wà ní Júdà.+