- 
	                        
            
            Àìsáyà 6:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Ó fèsì pé: “Lọ, kí o sì sọ fún àwọn èèyàn yìí pé: 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Mátíù 13:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        13 Ìdí nìyẹn tí mo fi ń fi àpèjúwe bá wọn sọ̀rọ̀; torí ní ti bí wọ́n ṣe ń wò, lásán ni wọ́n ń wò, ní ti bí wọ́n ṣe ń gbọ́, lásán ni wọ́n ń gbọ́, kò sì yé wọn.+ 
 
-