ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 6:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ó fèsì pé: “Lọ, kí o sì sọ fún àwọn èèyàn yìí pé:

      ‘Ẹ máa gbọ́ léraléra,

      Àmọ́ kò ní yé yín;

      Ẹ máa rí léraléra,

      Àmọ́ ẹ ò ní mọ nǹkan kan.’+

      10 Mú kí ọkàn àwọn èèyàn yìí yigbì,+

      Mú kí etí wọn di,+

      Kí o sì lẹ ojú wọn pọ̀,

      Kí wọ́n má bàa fi ojú wọn ríran,

      Kí wọ́n má sì fi etí wọn gbọ́rọ̀,

      Kí ọkàn wọn má bàa lóye,

      Kí wọ́n má bàa yí pa dà, kí wọ́n sì rí ìwòsàn.”+

  • Jeremáyà 5:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “Ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yin òmùgọ̀ àti aláìlọ́gbọ́n:*+

      Wọ́n ní ojú, ṣùgbọ́n wọn kò lè ríran;+

      Wọ́n ní etí, ṣùgbọ́n wọn kò lè gbọ́ràn.+

  • Róòmù 11:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ọlọ́run ti fún wọn ní ẹ̀mí oorun àsùnwọra,+ ojú tí kò ríran àti etí tí kò gbọ́ràn, títí di òní olónìí.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́