-
Jóòbù 38:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ta ló sì fi àwọn ilẹ̀kùn sé òkun,+
Nígbà tó tú jáde látinú ikùn,*
-
Sáàmù 33:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ó gbá omi òkun jọ bí ìsédò;+
Ó fi omi tó ń ru gùdù sínú àwọn ilé ìṣúra.
-
-
-