-
Sáàmù 95:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ogójì (40) ọdún ni mo fi kórìíra ìran yẹn, mo sì sọ pé:
“Àwọn èèyàn tó máa ń ṣìnà nínú ọkàn wọn ni wọ́n;
Wọn ò tíì mọ àwọn ọ̀nà mi.”
-
-
Jeremáyà 11:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ṣùgbọ́n wọn ò tẹ́tí sí mi, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò fetí sílẹ̀. Kàkà bẹ́ẹ̀, kálukú wọn ya alágídí, wọ́n sì ń ṣe ohun tí ọkàn búburú wọn sọ.+ Torí náà, mo mú gbogbo ọ̀rọ̀ májẹ̀mú yìí wá sórí wọn, èyí tí mo pa láṣẹ fún wọn, tí wọn ò sì pa mọ́.’”
-