-
Ìsíkíẹ́lì 13:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 “Ìran èké ni wọ́n rí, àsọtẹ́lẹ̀ irọ́ ni wọ́n sì sọ, àwọn tó ń sọ pé, ‘Ọ̀rọ̀ Jèhófà ni pé,’ tó sì jẹ́ pé Jèhófà ò rán wọn, wọ́n sì ti dúró kí ọ̀rọ̀ wọn lè ṣẹ.+
-