-
Jeremáyà 4:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ẹ ròyìn rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni, ẹ ròyìn rẹ̀ fún àwọn orílẹ̀-èdè;
Ẹ kéde rẹ̀ sórí Jerúsálẹ́mù.”
“Àwọn ẹ̀ṣọ́* ń bọ̀ láti ilẹ̀ tó jìnnà,
Wọ́n á sì gbé ohùn wọn sókè sí àwọn ìlú Júdà.
-