6 Ẹ pa àwọn àgbàlagbà ọkùnrin pátápátá àti àwọn géńdé ọkùnrin, wúńdíá, ọmọdé àti àwọn obìnrin.+ Àmọ́ ẹ má ṣe sún mọ́ ẹnikẹ́ni tí àmì náà wà lórí rẹ̀.+ Ibi mímọ́ mi ni kí ẹ ti bẹ̀rẹ̀.”+ Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ látorí àwọn àgbààgbà tí wọ́n wà níwájú ilé náà.+