2 Àwọn Ọba 25:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Olórí ẹ̀ṣọ́ tún mú Seráyà+ olórí àlùfáà àti Sefanáyà+ àlùfáà kejì pẹ̀lú àwọn aṣọ́nà mẹ́ta.+ 2 Àwọn Ọba 25:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọba Bábílónì ṣá wọn balẹ̀, ó sì pa wọ́n ní Ríbúlà ní ilẹ̀ Hámátì.+ Bí Júdà ṣe lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀ nìyẹn.+ Jeremáyà 25:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Nítorí tó bá jẹ́ pé ìlú tí à ń fi orúkọ mi+ pè ni màá kọ́kọ́ mú àjálù bá, ṣé ẹ̀yin á wá lọ láìjìyà ni?”’+ “‘Ẹ ò ní lọ láìjìyà, nítorí màá pe idà wá bá gbogbo àwọn tó ń gbé láyé,’ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.
21 Ọba Bábílónì ṣá wọn balẹ̀, ó sì pa wọ́n ní Ríbúlà ní ilẹ̀ Hámátì.+ Bí Júdà ṣe lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀ nìyẹn.+
29 Nítorí tó bá jẹ́ pé ìlú tí à ń fi orúkọ mi+ pè ni màá kọ́kọ́ mú àjálù bá, ṣé ẹ̀yin á wá lọ láìjìyà ni?”’+ “‘Ẹ ò ní lọ láìjìyà, nítorí màá pe idà wá bá gbogbo àwọn tó ń gbé láyé,’ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.