-
Jeremáyà 9:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Torí náà, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí:
“Màá yọ́ wọn mọ́, màá sì yẹ̀ wọ́n wò,+
Àbí kí ni kí n tún ṣe sí ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi?
-
-
Ìsíkíẹ́lì 22:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Bí ìgbà tí wọ́n bá kó fàdákà, bàbà, irin, òjé àti tánganran jọ sínú iná ìléru, kí wọ́n lè koná mọ́ ọn kí wọ́n sì yọ́ ọ, bẹ́ẹ̀ ni màá fi ìbínú àti ìrunú kó yín jọ, màá koná mọ́ yín, màá sì yọ́ yín.+
-