Àìsáyà 1:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Màá yí ọwọ́ mi pa dà sí ọ,Màá yọ́ ìdàrọ́ rẹ dà nù bíi pé mo fi ọṣẹ fọ ìdọ̀tí,Màá sì mú gbogbo ìdọ̀tí rẹ kúrò.+ Àìsáyà 48:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wò ó! Mo ti yọ́ ọ mọ́, àmọ́ kì í ṣe bíi ti fàdákà.+ Mo ti dán ọ wò* nínú iná ìléru ti ìyà, tí a fi ń yọ́ nǹkan.+
25 Màá yí ọwọ́ mi pa dà sí ọ,Màá yọ́ ìdàrọ́ rẹ dà nù bíi pé mo fi ọṣẹ fọ ìdọ̀tí,Màá sì mú gbogbo ìdọ̀tí rẹ kúrò.+
10 Wò ó! Mo ti yọ́ ọ mọ́, àmọ́ kì í ṣe bíi ti fàdákà.+ Mo ti dán ọ wò* nínú iná ìléru ti ìyà, tí a fi ń yọ́ nǹkan.+