-
1 Sámúẹ́lì 4:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Yàtọ̀ síyẹn, wọ́n gba Àpótí Ọlọ́run, àwọn ọmọ Élì méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì sì kú.+
-
-
Jeremáyà 26:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Kí nìdí tí o fi sọ tẹ́lẹ̀ ní orúkọ Jèhófà, pé, ‘Ilé yìí máa dà bíi Ṣílò, ìlú yìí á sì di ahoro tí kò ní sí ẹnì kankan tí á máa gbé ibẹ̀’?” Gbogbo àwọn èèyàn náà sì pé jọ yí Jeremáyà ká ní ilé Jèhófà.
-