Diutarónómì 28:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 O máa fẹ́ obìnrin sọ́nà, àmọ́ ọkùnrin míì á fipá bá a lò pọ̀. O máa kọ́ ilé, àmọ́ o ò ní gbé ibẹ̀.+ O máa gbin àjàrà, àmọ́ o ò ní rí i lò.+ Sefanáyà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n á kó ọrọ̀ wọn lọ, wọ́n á sì pa ilé wọn run.+ Wọ́n á kọ́ ilé, ṣùgbọ́n wọn kò ní gbé inú rẹ̀;Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, ṣùgbọ́n wọn kò ní mu wáìnì rẹ̀.+
30 O máa fẹ́ obìnrin sọ́nà, àmọ́ ọkùnrin míì á fipá bá a lò pọ̀. O máa kọ́ ilé, àmọ́ o ò ní gbé ibẹ̀.+ O máa gbin àjàrà, àmọ́ o ò ní rí i lò.+
13 Wọ́n á kó ọrọ̀ wọn lọ, wọ́n á sì pa ilé wọn run.+ Wọ́n á kọ́ ilé, ṣùgbọ́n wọn kò ní gbé inú rẹ̀;Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, ṣùgbọ́n wọn kò ní mu wáìnì rẹ̀.+