-
Jeremáyà 16:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nípa àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin tí wọ́n bí ní ibí yìí àti nípa àwọn ìyá wọn àti àwọn bàbá wọn tó bí wọn ní ilẹ̀ yìí ni pé: 4 ‘Àrùn burúkú ni yóò pa wọ́n,+ ẹnì kankan ò ní ṣọ̀fọ̀ wọn, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò ní sin wọ́n; wọ́n á dà bí ajílẹ̀ lórí ilẹ̀.+ Idà àti ìyàn ni yóò pa wọ́n,+ òkú wọn yóò sì di oúnjẹ fún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti àwọn ẹranko orí ilẹ̀.’
-