-
Diutarónómì 1:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
1 Èyí ni àwọn ọ̀rọ̀ tí Mósè bá gbogbo Ísírẹ́lì sọ ní agbègbè Jọ́dánì nínú aginjù, ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú níwájú Súfù, láàárín Páránì, Tófélì, Lábánì, Hásérótì àti Dísáhábù.
-