Jeremáyà 30:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Nítorí mo wà pẹ̀lú rẹ,” ni Jèhófà wí, “láti gbà ọ́. Ṣùgbọ́n màá pa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí mo tú ọ ká sí àárín wọn run;+Àmọ́ ní tìrẹ, mi ò ní pa ọ́ run.+ Mi ò ní bá ọ wí* kọjá ààlà,Mi ò sì ní ṣàìfi ìyà jẹ ọ́.”+
11 “Nítorí mo wà pẹ̀lú rẹ,” ni Jèhófà wí, “láti gbà ọ́. Ṣùgbọ́n màá pa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí mo tú ọ ká sí àárín wọn run;+Àmọ́ ní tìrẹ, mi ò ní pa ọ́ run.+ Mi ò ní bá ọ wí* kọjá ààlà,Mi ò sì ní ṣàìfi ìyà jẹ ọ́.”+