Léfítíkù 26:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Àmọ́ láìka gbogbo èyí sí, nígbà tí wọ́n ṣì wà ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn, mi ò ní kọ̀ wọ́n pátápátá+ tàbí kí n ta wọ́n nù débi pé màá pa wọ́n run pátápátá, torí ìyẹn á da májẹ̀mú tí mo bá wọn dá,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run wọn. Nehemáyà 9:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nínú àánú ńlá rẹ, o ò pa wọ́n run,+ o ò sì fi wọ́n sílẹ̀, nítorí Ọlọ́run tó ń gba tẹni rò* àti aláàánú ni ọ́.+ Ìdárò 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ ni ò jẹ́ ká ṣègbé,+Nítorí àánú rẹ̀ kò ní dópin láé.+ Émọ́sì 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 ‘Wò ó! Ojú Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára ìjọba tó ń dẹ́ṣẹ̀,Á sì pa á rẹ́ kúrò lórí ilẹ̀.+ Ṣùgbọ́n, mi ò ní pa gbogbo ilé Jékọ́bù rẹ́,’+ ni Jèhófà wí.
44 Àmọ́ láìka gbogbo èyí sí, nígbà tí wọ́n ṣì wà ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn, mi ò ní kọ̀ wọ́n pátápátá+ tàbí kí n ta wọ́n nù débi pé màá pa wọ́n run pátápátá, torí ìyẹn á da májẹ̀mú tí mo bá wọn dá,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run wọn.
31 Nínú àánú ńlá rẹ, o ò pa wọ́n run,+ o ò sì fi wọ́n sílẹ̀, nítorí Ọlọ́run tó ń gba tẹni rò* àti aláàánú ni ọ́.+
8 ‘Wò ó! Ojú Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára ìjọba tó ń dẹ́ṣẹ̀,Á sì pa á rẹ́ kúrò lórí ilẹ̀.+ Ṣùgbọ́n, mi ò ní pa gbogbo ilé Jékọ́bù rẹ́,’+ ni Jèhófà wí.