-
Jeremáyà 8:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 À ń gbọ́ bí àwọn ẹṣin wọn ṣe ń fọn imú láti Dánì.
Nígbà tí àwọn akọ ẹṣin rẹ̀ bá yán,
Ìró wọn á mú gbogbo ilẹ̀ náà mì tìtì.
Wọ́n wọlé wá, wọ́n sì jẹ ilẹ̀ náà run àti gbogbo ohun tó wà lórí rẹ̀,
Ìlú náà àti àwọn tó ń gbé inú rẹ̀.”
-
-
Ìdárò 2:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 O ránṣẹ́ pe ohun ẹ̀rù láti ibi gbogbo wá, bí ìgbà tí à ń peni sí ọjọ́ àjọyọ̀.+
-