Diutarónómì 28:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Ègún máa wà lórí àwọn ọmọ*+ rẹ, èso ilẹ̀ rẹ, ọmọ màlúù àti àgùntàn+ rẹ.