Ẹ́kísódù 13:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mósè wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ máa rántí ọjọ́ yìí tí ẹ kúrò ní Íjíbítì,+ ní ilé ẹrú, torí ọwọ́ agbára ni Jèhófà fi mú yín kúrò níbí.+ Torí náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tó ní ìwúkàrà. Diutarónómì 4:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ ẹ̀yin ni Jèhófà mú jáde nínú iná ìléru tí wọ́n ti ń yọ́ irin, kúrò nílẹ̀ Íjíbítì, kí ẹ lè di ohun ìní rẹ̀*+ bí ẹ ṣe jẹ́ lónìí.
3 Mósè wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ máa rántí ọjọ́ yìí tí ẹ kúrò ní Íjíbítì,+ ní ilé ẹrú, torí ọwọ́ agbára ni Jèhófà fi mú yín kúrò níbí.+ Torí náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tó ní ìwúkàrà.
20 Àmọ́ ẹ̀yin ni Jèhófà mú jáde nínú iná ìléru tí wọ́n ti ń yọ́ irin, kúrò nílẹ̀ Íjíbítì, kí ẹ lè di ohun ìní rẹ̀*+ bí ẹ ṣe jẹ́ lónìí.