-
Diutarónómì 32:37, 38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Ó máa wá sọ pé, ‘Àwọn ọlọ́run+ wọn dà,
Àpáta tí wọ́n sá di,
38 Tó máa ń jẹ ọ̀rá àwọn ẹbọ wọn,*
Tó ń mu wáìnì ọrẹ ohun mímu+ wọn?
Jẹ́ kí wọ́n dìde wá ràn yín lọ́wọ́.
Kí wọ́n di ibi ààbò fún yín.
-