Jeremáyà 11:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí pé bí ìlú rẹ ṣe pọ̀ tó ni àwọn ọlọ́run rẹ ṣe pọ̀ tó, ìwọ Júdà, o sì ti ṣe pẹpẹ tó pọ̀ bí àwọn ojú ọ̀nà Jerúsálẹ́mù ṣe pọ̀ fún ohun ìtìjú* láti máa fi rú ẹbọ sí Báálì.’+
13 Torí pé bí ìlú rẹ ṣe pọ̀ tó ni àwọn ọlọ́run rẹ ṣe pọ̀ tó, ìwọ Júdà, o sì ti ṣe pẹpẹ tó pọ̀ bí àwọn ojú ọ̀nà Jerúsálẹ́mù ṣe pọ̀ fún ohun ìtìjú* láti máa fi rú ẹbọ sí Báálì.’+