9 Ṣé ẹ lè máa jalè+ tàbí kí ẹ máa pa èèyàn, kí ẹ máa ṣe àgbèrè tàbí kí ẹ máa búra èké,+ kí ẹ máa rú ẹbọ sí Báálì,+ kí ẹ sì máa tẹ̀ lé àwọn ọlọ́run míì tí ẹ kò mọ̀, 10 kí ẹ wá dúró níwájú mi nínú ilé yìí tí a fi orúkọ mi pè, kí ẹ sì sọ pé, ‘A ó rí ìgbàlà,’ pẹ̀lú gbogbo ohun ìríra tí ẹ ti ṣe yìí?