Àìsáyà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó gbẹ́ ibẹ̀, ó sì kó àwọn òkúta ibẹ̀ kúrò. Ó gbin àjàrà pupa tó dáa sínú rẹ̀,Ó kọ́ ilé gogoro sí àárín rẹ̀,Ó sì gbẹ́ ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì sínú rẹ̀.+ Ó wá ń retí pé kí àjàrà náà so,Àmọ́ èso àjàrà igbó nìkan ló mú jáde. + Jeremáyà 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mo gbìn ọ́ bí àjàrà pupa tó dára,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ èso tí kò lábùkù;Báwo lo ṣe wá di ọ̀mùnú àjàrà ilẹ̀ òkèèrè tí kò dára lójú mi?’+
2 Ó gbẹ́ ibẹ̀, ó sì kó àwọn òkúta ibẹ̀ kúrò. Ó gbin àjàrà pupa tó dáa sínú rẹ̀,Ó kọ́ ilé gogoro sí àárín rẹ̀,Ó sì gbẹ́ ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì sínú rẹ̀.+ Ó wá ń retí pé kí àjàrà náà so,Àmọ́ èso àjàrà igbó nìkan ló mú jáde. +
21 Mo gbìn ọ́ bí àjàrà pupa tó dára,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ èso tí kò lábùkù;Báwo lo ṣe wá di ọ̀mùnú àjàrà ilẹ̀ òkèèrè tí kò dára lójú mi?’+