-
Jeremáyà 23:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “Mo ti rí ohun ìríra nínú àwọn wòlíì Samáríà.+
Báálì ló ń mú kí wọ́n lè sọ àsọtẹ́lẹ̀,
Wọ́n sì ń kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì ṣìnà.
-