Àìsáyà 63:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó jẹ́ ti àwọn èèyàn mímọ́ rẹ fúngbà díẹ̀. Àwọn ọ̀tá wa ti tẹ ibi mímọ́ rẹ mọ́lẹ̀.+ Jeremáyà 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Mo sọ lọ́kàn mi pé, ‘Wo bí mo ṣe fi ọ́ sáàárín àwọn ọmọ tí mo sì fún ọ ní ilẹ̀ tó dára, ogún tó rẹwà láàárín àwọn orílẹ̀-èdè!’*+ Mo tún sọ lọ́kàn mi pé, ẹ ó pè mí ní, ‘Bàbá mi!’ ẹ kò sì ní pa dà lẹ́yìn mi.
19 Mo sọ lọ́kàn mi pé, ‘Wo bí mo ṣe fi ọ́ sáàárín àwọn ọmọ tí mo sì fún ọ ní ilẹ̀ tó dára, ogún tó rẹwà láàárín àwọn orílẹ̀-èdè!’*+ Mo tún sọ lọ́kàn mi pé, ẹ ó pè mí ní, ‘Bàbá mi!’ ẹ kò sì ní pa dà lẹ́yìn mi.