2 Kíróníkà 36:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sun ilé Ọlọ́run tòótọ́ kanlẹ̀,+ ó wó ògiri Jerúsálẹ́mù lulẹ̀,+ ó sun gbogbo àwọn ilé gogoro tó láàbò, ó sì ba gbogbo ohun tó ṣeyebíye jẹ́.+ Àìsáyà 64:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ilé* wa mímọ́ àti ológo,*Tí àwọn baba ńlá wa ti yìn ọ́,Ni wọ́n ti dáná sun,+Gbogbo àwọn ohun tó ṣeyebíye sí wa sì ti pa run. Ìdárò 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Elénìní ti kó gbogbo ìṣúra rẹ̀.+ Nítorí ìṣojú rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè wá sínú ibi mímọ́ rẹ̀,+Àwọn tí o pàṣẹ pé kí wọ́n má ṣe wá sínú ìjọ rẹ.
19 Ó sun ilé Ọlọ́run tòótọ́ kanlẹ̀,+ ó wó ògiri Jerúsálẹ́mù lulẹ̀,+ ó sun gbogbo àwọn ilé gogoro tó láàbò, ó sì ba gbogbo ohun tó ṣeyebíye jẹ́.+
11 Ilé* wa mímọ́ àti ológo,*Tí àwọn baba ńlá wa ti yìn ọ́,Ni wọ́n ti dáná sun,+Gbogbo àwọn ohun tó ṣeyebíye sí wa sì ti pa run.
10 Elénìní ti kó gbogbo ìṣúra rẹ̀.+ Nítorí ìṣojú rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè wá sínú ibi mímọ́ rẹ̀,+Àwọn tí o pàṣẹ pé kí wọ́n má ṣe wá sínú ìjọ rẹ.