ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32:37, 38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  37 Ó máa wá sọ pé, ‘Àwọn ọlọ́run+ wọn dà,

      Àpáta tí wọ́n sá di,

       38 Tó máa ń jẹ ọ̀rá àwọn ẹbọ wọn,*

      Tó ń mu wáìnì ọrẹ ohun mímu+ wọn?

      Jẹ́ kí wọ́n dìde wá ràn yín lọ́wọ́.

      Kí wọ́n di ibi ààbò fún yín.

  • Àìsáyà 28:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Nítorí ẹ sọ pé:

      “A ti bá Ikú dá májẹ̀mú,+

      A sì ti bá Isà Òkú* ṣe àdéhùn.*

      Tí omi tó ń ru gùdù bá ya kọjá lójijì,

      Kò ní dé ọ̀dọ̀ wa,

      Torí a ti fi irọ́ ṣe ibi ààbò wa,

      A sì ti fi ara wa pa mọ́ sínú èké.”+

  • Jeremáyà 10:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Kálukú ń hùwà láìronú, wọn ò sì ní ìmọ̀.

      Ojú á ti gbogbo oníṣẹ́ irin nítorí ère tí wọ́n ṣe;+

      Nítorí ère onírin* rẹ̀ jẹ́ èké,

      Kò sì sí ẹ̀mí* kankan nínú wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́