-
Jeremáyà 12:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ìgbà wo ni ilẹ̀ náà kò ní ṣá mọ́
Tí koríko gbogbo ilẹ̀ kò sì ní gbẹ dà nù?+
Nítorí ìwà ibi àwọn tó ń gbé lórí rẹ̀,
A ti gbá àwọn ẹranko àti àwọn ẹyẹ lọ.
Torí wọ́n sọ pé: “Kò rí ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí wa.”
-
-
Jóẹ́lì 1:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Kódà, àwọn ẹran ọ̀sìn ń kérora!
Ìdààmú bá àwọn agbo màlúù, wọ́n sì ń rìn gbéregbère torí wọn ò rí ewéko jẹ.
Àwọn agbo àgùntàn sì jẹ nínú ìyà náà.
-