ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 14:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó dúró lórí àwọn òkè.

      Wọ́n ń mí hẹlẹhẹlẹ bí ajáko;*

      Ojú wọn ò ríran dáadáa torí pé kò sí ewéko.+

  • Jeremáyà 23:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Nítorí àwọn alágbèrè ló kún ilẹ̀ náà;+

      Nítorí ègún, ilẹ̀ náà ti bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀+

      Àwọn ibi ìjẹko inú aginjù ti gbẹ.+

      Ọ̀nà wọn jẹ́ ibi, wọ́n sì ń ṣi agbára wọn lò.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́