Jeremáyà 6:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Kò já mọ́ nǹkan kan lójú mi pé ẹ̀ ń mú oje igi tùràrí wá láti ṢébàÀti pòròpórò olóòórùn dídùn* láti ilẹ̀ tó jìnnà. Àwọn odindi ẹbọ sísun yín kò ní ìtẹ́wọ́gbà,Àwọn ẹbọ yín kò sì mú inú mi dùn.”+
20 “Kò já mọ́ nǹkan kan lójú mi pé ẹ̀ ń mú oje igi tùràrí wá láti ṢébàÀti pòròpórò olóòórùn dídùn* láti ilẹ̀ tó jìnnà. Àwọn odindi ẹbọ sísun yín kò ní ìtẹ́wọ́gbà,Àwọn ẹbọ yín kò sì mú inú mi dùn.”+