- 
	                        
            
            Àìsáyà 66:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Ẹni tó ń pa akọ màlúù dà bí ẹni tó ń ṣá èèyàn balẹ̀.+ Ẹni tó ń fi àgùntàn rúbọ dà bí ẹni tó ń ṣẹ́ ọrùn ajá.+ Ẹni tó ń mú ẹ̀bùn wá dà bí ẹni tó ń fi ẹ̀jẹ̀ ẹlẹ́dẹ̀ rúbọ!+ Ẹni tó ń mú oje igi tùràrí wá láti fi ṣe ọrẹ ìrántí+ dà bí ẹni tó ń fi ọfọ̀ súre.*+ Wọ́n ti yan ọ̀nà tiwọn, Ohun ìríra ló sì ń múnú wọn dùn.* 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 7:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        21 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Ẹ lọ, kí ẹ fi odindi ẹbọ sísun yín kún àwọn ẹbọ yín yòókù, kí ẹ sì jẹ ẹran rẹ̀.+ 
 
-