-
Jeremáyà 8:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ẹ̀dùn ọkàn mi kò ṣeé wò sàn;
Ọkàn mi ń ṣàárẹ̀.
-
-
Jeremáyà 8:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Ẹ̀dùn ọkàn bá mi nítorí àárẹ̀ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi;+
Ìbànújẹ́ sorí mi kodò.
Àyà fò mí torí ìbẹ̀rù.
-
-
Jeremáyà 9:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ká ní orí mi jẹ́ omi,
Tí ojú mi sì jẹ́ orísun omijé!+
Mi ò bá sunkún tọ̀sántòru
Nítorí àwọn èèyàn mi tí wọ́n pa.
-