Jeremáyà 4:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìrora mi pọ̀,* ìrora mi pọ̀! Ọkàn mi* gbọgbẹ́. Àyà mi ń lù kìkì. Mi ò lè dákẹ́,Nítorí mo* ti gbọ́ ìró ìwo Àti ìró ogun.*+ 20 Àjálù lórí àjálù ni ìròyìn tí à ń gbọ́,Nítorí pé wọ́n ti pa gbogbo ilẹ̀ náà run. Lójijì, wọ́n pa àgọ́ mi run,Ní ìṣẹ́jú kan, wọ́n pa aṣọ àgọ́ mi run.+ Jeremáyà 14:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn pé,‘Kí omijé ṣàn ní ojú mi tọ̀sántòru, kí ó má sì dá,+Nítorí wọ́n ti lu wúńdíá àwọn èèyàn mi ní àlùbolẹ̀,+Wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna.
19 Ìrora mi pọ̀,* ìrora mi pọ̀! Ọkàn mi* gbọgbẹ́. Àyà mi ń lù kìkì. Mi ò lè dákẹ́,Nítorí mo* ti gbọ́ ìró ìwo Àti ìró ogun.*+ 20 Àjálù lórí àjálù ni ìròyìn tí à ń gbọ́,Nítorí pé wọ́n ti pa gbogbo ilẹ̀ náà run. Lójijì, wọ́n pa àgọ́ mi run,Ní ìṣẹ́jú kan, wọ́n pa aṣọ àgọ́ mi run.+
17 “Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn pé,‘Kí omijé ṣàn ní ojú mi tọ̀sántòru, kí ó má sì dá,+Nítorí wọ́n ti lu wúńdíá àwọn èèyàn mi ní àlùbolẹ̀,+Wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna.