34 Màá fòpin sí ìró ayọ̀ àti ìró ìdùnnú, ohùn ọkọ ìyàwó àti ohùn ìyàwó+ ní àwọn ìlú Júdà àti ní àwọn ojú ọ̀nà Jerúsálẹ́mù, nítorí ilẹ̀ náà yóò di ahoro.’”+
23 Iná fìtílà kankan ò ní tàn nínú rẹ mọ́ láé, a ò sì ní gbọ́ ohùn ọkọ ìyàwó àti ìyàwó nínú rẹ mọ́ láé; torí àwọn ọkùnrin tó wà nípò gíga ní ayé ni àwọn oníṣòwò rẹ, ìwà ìbẹ́mìílò+ rẹ sì ṣi gbogbo orílẹ̀-èdè lọ́nà.