Sáàmù 73:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní tòótọ́, àwọn tó jìnnà sí ọ yóò ṣègbé. Gbogbo àwọn tó fi ọ́ sílẹ̀ lọ ṣe ìṣekúṣe* ni wàá pa run.*+ Àìsáyà 1:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Àwọn ọlọ̀tẹ̀ àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ jọ máa fọ́ sí wẹ́wẹ́,+Òpin sì máa dé bá àwọn tó ń fi Jèhófà sílẹ̀.+
27 Ní tòótọ́, àwọn tó jìnnà sí ọ yóò ṣègbé. Gbogbo àwọn tó fi ọ́ sílẹ̀ lọ ṣe ìṣekúṣe* ni wàá pa run.*+