Ẹ́sírà 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí náà, wọ́n mọ pẹpẹ náà sí ibi tó wà tẹ́lẹ̀, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀rù àwọn orílẹ̀-èdè tó yí wọn ká ń bà wọ́n,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í rú àwọn ẹbọ sísun sí Jèhófà lórí rẹ̀, àwọn ẹbọ sísun òwúrọ̀ àti ti ìrọ̀lẹ́.+
3 Nítorí náà, wọ́n mọ pẹpẹ náà sí ibi tó wà tẹ́lẹ̀, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀rù àwọn orílẹ̀-èdè tó yí wọn ká ń bà wọ́n,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í rú àwọn ẹbọ sísun sí Jèhófà lórí rẹ̀, àwọn ẹbọ sísun òwúrọ̀ àti ti ìrọ̀lẹ́.+