Jeremáyà 15:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ìwọ fúnra rẹ mọ̀, Jèhófà,Rántí mi kí o sì kíyè sí mi. Gbẹ̀san mi lára àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi.+ Má ṣe jẹ́ kí n ṣègbé* torí o kì í tètè bínú. O ṣáà mọ̀ pé nítorí rẹ ni mo ṣe ń fara da ẹ̀gàn yìí.+
15 Ìwọ fúnra rẹ mọ̀, Jèhófà,Rántí mi kí o sì kíyè sí mi. Gbẹ̀san mi lára àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi.+ Má ṣe jẹ́ kí n ṣègbé* torí o kì í tètè bínú. O ṣáà mọ̀ pé nítorí rẹ ni mo ṣe ń fara da ẹ̀gàn yìí.+