-
Jeremáyà 11:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Jẹ́ kí n rí ẹ̀san rẹ lára wọn,
Nítorí ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹjọ́ mi lé.
-
-
Jeremáyà 12:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Mú wọn bí àgùntàn tí wọ́n fẹ́ lọ pa,
Kí o sì yà wọ́n sọ́tọ̀ fún ọjọ́ pípa.
-
-
Jeremáyà 17:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Jẹ́ kí ojú ti àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi,+
Àmọ́ má ṣe jẹ́ kí ojú tì mí.
Jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá wọn,
Àmọ́ má ṣe jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá mi.
-